Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) Not Available
Removed from the App Store
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

Andrew Blurton

1.2 for iPhone, iPad
6.0

2 Ratings

Release Date

2017-09-13

Size

54.1 MB

Screenshots for iPhone

More Screenshots for iPad
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) Description
Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.


Wa’di
O le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ.


Fi awọn ẹsẹ han lori Facebook, Twitter ati Email


Ni bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han).


Kọ Adura ati awon ero

Ọpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn. Ṣẹda adura arare ati ero re, fi wọn pamọ sinu awọn ‘app’ ati paapa fi wọn han si awọn ọrẹ rẹ lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ email


Isaami si ẹsẹ


Nibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ. kọ rọra tẹ aworan geege nigba ti o ba n ka ọrọ Bibeli lọwọ

Bayi o le ri ese ti o yatọ ninu àwo ti o fẹ. Ko tẹ awọn aami ohun elo ikọwe bi o ba ka awọn ọrọ Bibeli

Bukumaaki


Bukumaaki yio ran ọ lọwọ lati sami si ibi tire ninu ọrọ bibeli. Awọn aami bukumaaki yi ni owa loke iboju. kọ fi ika tọ lati sami sori rẹ. Nigba ti o ba pada si ‘app’ tẹ aami ti owa loke ti iboju, yio si gbe ọ lọ sibi ti o ti kuro.


Wa ki o si se afiwe awọn ẹsẹ (Ni App)
Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won.


Ọpa Ìkẹkọọ - Išė Akojọ

Ṣẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ. Fi iwadi rẹ si ẹgbẹẹ àwọn ẹsẹ ọun. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’.
Eda King James ni ede oyiboKa bibeli ti eda King James ni ede oyibo. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo.


Pe Wa


A n reti awọn esi rẹ. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin. O le fi iwe ranṣẹ si wa nipasẹ awọn olubasọrọ wa ninu iṣẹ ‘app’ yi.
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) 1.2 Update
2017-09-13 Version History
Verse of the Day
More
More Information
Price:
$2.99
Version:
1.2
Size:
54.1 MB
Genre:
Education Books
Release Date:
2017-09-13
Developer:
Andrew Blurton
Language:
English
More
In-App Purchases:

Awọn Ọba James Bible in English $0.99

Compare and Search Verses $1.99

Ilé ìkàwé $1.99

Gbogbo ìṣe $3.99

Apocrypha (English) $0.99

Adura iṣeto ati itaniji $0.99

More
You May Also Like
Developer Apps