Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)
$2.99
1.2for iPhone, iPad
Age Rating
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) 스크린 샷
About Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)
Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.
Wa’di
O le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ.
Fi awọn ẹsẹ han lori Facebook, Twitter ati Email
Ni bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han).
Kọ Adura ati awon ero
Ọpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn. Ṣẹda adura arare ati ero re, fi wọn pamọ sinu awọn ‘app’ ati paapa fi wọn han si awọn ọrẹ rẹ lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ email
Isaami si ẹsẹ
Nibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ. kọ rọra tẹ aworan geege nigba ti o ba n ka ọrọ Bibeli lọwọ
Bayi o le ri ese ti o yatọ ninu àwo ti o fẹ. Ko tẹ awọn aami ohun elo ikọwe bi o ba ka awọn ọrọ Bibeli
Bukumaaki
Bukumaaki yio ran ọ lọwọ lati sami si ibi tire ninu ọrọ bibeli. Awọn aami bukumaaki yi ni owa loke iboju. kọ fi ika tọ lati sami sori rẹ. Nigba ti o ba pada si ‘app’ tẹ aami ti owa loke ti iboju, yio si gbe ọ lọ sibi ti o ti kuro.
Wa ki o si se afiwe awọn ẹsẹ (Ni App)
Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won.
Ọpa Ìkẹkọọ - Išė Akojọ
Ṣẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ. Fi iwadi rẹ si ẹgbẹẹ àwọn ẹsẹ ọun. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’.
Eda King James ni ede oyibo
Ka bibeli ti eda King James ni ede oyibo. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo.
Pe Wa
A n reti awọn esi rẹ. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin. O le fi iwe ranṣẹ si wa nipasẹ awọn olubasọrọ wa ninu iṣẹ ‘app’ yi.

Show More
최신 버전 1.2의 새로운 기능
Last updated on Sep 13, 2017
오래된 버전
Verse of the Day
Show More
Version History
1.2
Sep 13, 2017
Verse of the Day
1.1
Jan 22, 2016
A ti redesigned awọn app ati ki o fi kun a ojoojumọ lokun ẹsẹ ẹya-ara ati da a adura iṣeto itaniji. We have redesigned the app and added a daily inspirational verse feature and created a prayer schedule alarm
1.0
May 6, 2015
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) FAQ
제한된 국가 또는 지역에서 Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)를 다운로드하는 방법을 알아보려면 여기를 클릭하십시오.
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)의 최소 요구 사항을 보려면 다음 목록을 확인하십시오.
iPhone
iPad
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)은 다음 언어를 지원합니다. English